Samuẹli Keji 23:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mìíràn tí wọ́n tún jẹ́ ara “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni” náà nìwọ̀nyí: Asaheli arakunrin Joabu, ati Elihanani, ọmọ Dodo, ará Bẹtilẹhẹmu.

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:15-34