Samuẹli Keji 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni ó jẹ́ olókìkí jùlọ ninu “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni,” ó sì di aṣiwaju wọn, ṣugbọn kò lókìkí tó “Àwọn Akọni Mẹta” àkọ́kọ́.

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:11-29