Samuẹli Keji 23:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn Ṣama dúró gbọningbọnin ní ojú ogun. Ó jà kíkankíkan, ó sì pa àwọn ará Filistia. OLUWA sì ja àjàṣẹ́gun ńlá ní ọjọ́ náà.

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:10-14