Samuẹli Keji 23:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ ìkẹyìn Dafidi nìyí; àní, ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ Dafidi, ọmọ Jese, tí a gbé ga ní Israẹli, ẹni àmì òróró Ọlọrun Jakọbu, olórin dídùn ní Israẹli:

Samuẹli Keji 23

Samuẹli Keji 23:1-8