Samuẹli Keji 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Èéfín jáde láti ihò imú rẹ̀,iná ajónirun sì jáde láti ẹnu rẹ̀;ẹ̀yinná tí ó pọ́n rẹ̀rẹ̀ ń ti ọ̀dọ̀ rẹ̀ jáde.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:8-11