Samuẹli Keji 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìpọ́njú mi, mo ké pe OLUWAmo ké pe Ọlọrun mi,ó gbọ́ ohùn mi láti inú tẹmpili rẹ̀;ó sì tẹ́tí sí igbe mi.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:1-17