Samuẹli Keji 22:49 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì fà mí yọ lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.“OLUWA, ìwọ ni o gbé mi ga ju àwọn ọ̀tá mi lọ,o sì dáàbò bò mí, lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:41-51