Samuẹli Keji 22:47 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA wà láàyè,ìyìn ni fún àpáta ààbò mi.Ẹ gbé Ọlọrun mi ga,ẹni tíí ṣe àpáta ìgbàlà mi.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:38-50