Samuẹli Keji 22:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àjèjì ń wólẹ̀ níwájú mi,ẹsẹ̀kẹsẹ̀ tí wọ́n bá ti gbúròó mi, ni wọ́n ń mú àṣẹ mi ṣẹ.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:40-49