Samuẹli Keji 22:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá ìrànlọ́wọ́ káàkiri,ṣugbọn kò sí ẹni tí ó lè gbà wọ́n;wọ́n pe OLUWA,ṣugbọn kò dá wọn lóhùn.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:39-48