Samuẹli Keji 22:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo pa wọ́n run, mo bì wọ́n lulẹ̀;wọn kò sì lè dìde mọ́;wọ́n ṣubú lábẹ́ ẹsẹ̀ mi.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:34-49