Samuẹli Keji 22:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ti Ọlọrun yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀,òtítọ́ ni ìlérí OLUWA,ó sì jẹ́ apata fun gbogbo àwọn tí wọ́n bá sápamọ́ sábẹ́ ààbò rẹ̀.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:22-38