Samuẹli Keji 22:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ràn mí lọ́wọ́,ó kó mi yọ ninu ewu,ó sì gbà mí là,nítorí pé inú rẹ̀ dùn sí mi.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:19-26