Samuẹli Keji 22:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tá mi, tí ó lágbára;ati lọ́wọ́ gbogbo àwọn tí wọ́n kórìíra mi;nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:15-26