Samuẹli Keji 22:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìsàlẹ̀ òkun di gbangba, ìpìlẹ̀ ayé sì ṣí sílẹ̀,nígbà tí OLUWA bá wọn wí,tí ó sì fi ibinu jágbe mọ́ wọn.

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:9-19