Samuẹli Keji 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA gba Dafidi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ati lọ́wọ́ Saulu, Dafidi kọ orin yìí sí OLUWA pé:

Samuẹli Keji 22

Samuẹli Keji 22:1-3