Samuẹli Keji 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nítorí majẹmu tí ó wà láàrin Dafidi ati Jonatani, Dafidi kò fi ọwọ́ kan Mẹfiboṣẹti, ọmọ Jonatani, ọmọ Saulu.

Samuẹli Keji 21

Samuẹli Keji 21:4-9