Samuẹli Keji 21:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dáhùn pé, “Saulu fẹ́ pa wá run, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni ninu wa wà láàyè níbikíbi, ní ilẹ̀ Israẹli.

Samuẹli Keji 21

Samuẹli Keji 21:1-11