Samuẹli Keji 20:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun Joabu, ati àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun yòókù, tí wọ́n kù ní Jerusalẹmu bá tẹ̀lé Abiṣai láti lépa Ṣeba.

Samuẹli Keji 20

Samuẹli Keji 20:1-11