Samuẹli Keji 20:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Amasa pé, “Pe gbogbo àwọn ọkunrin Juda jọ, kí o sì kó wọn wá sọ́dọ̀ mi láàrin ọjọ́ mẹta; kí ìwọ náà sì wá.”

Samuẹli Keji 20

Samuẹli Keji 20:3-7