Samuẹli Keji 20:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Adoramu ni olórí àwọn tí wọ́n ń kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́. Jehoṣafati ọmọ Ahiludi ni olùtọ́jú àwọn àkọsílẹ̀ ní ààfin ọba.

Samuẹli Keji 20

Samuẹli Keji 20:21-26