Samuẹli Keji 20:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣeba la ilẹ̀ gbogbo ẹ̀yà Israẹli já, ó lọ sí ìlú Abeli ti Beti Maaka. Gbogbo àwọn ará Bikiri bá péjọ, wọ́n sì tẹ̀lé e wọnú ìlú náà.

Samuẹli Keji 20

Samuẹli Keji 20:9-22