Samuẹli Keji 2:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Joabu pada lẹ́yìn Abineri, tí ó sì kó gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ jọ, ó rí i pé, lẹ́yìn Asaheli, àwọn mejidinlogun ni wọn kò rí mọ́.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:24-32