Samuẹli Keji 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Asaheli bẹ̀rẹ̀ sí lé Abineri lọ, bí ó sì ti ń lé e lọ, kò wo ọ̀tún, bẹ́ẹ̀ ni kò wo òsì.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:11-23