Samuẹli Keji 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ogoji ọdún ni nígbà tí wọ́n fi jọba lórí Israẹli, ó sì wà lórí oyè fún ọdún meji.Ṣugbọn ẹ̀yìn Dafidi ni gbogbo ẹ̀yà Juda wà.

Samuẹli Keji 2

Samuẹli Keji 2:7-13