Samuẹli Keji 19:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Irú anfaani ńlá báyìí kò tọ́ sí mi láti ọ̀dọ̀ ọba, nítorí náà, n óo bá ọba gun òkè odò Jọdani, n óo sì bá ọ lọ sí iwájú díẹ̀ ni.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:29-37