Samuẹli Keji 19:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ pa irọ́ mọ́ mi lọ́dọ̀ ọba. Ṣugbọn bí angẹli Ọlọrun ni oluwa mi, ọba rí; nítorí náà, ṣe ohun tí ó bá tọ́ sí mi ní ojú rẹ.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:25-36