Samuẹli Keji 19:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo mọ̀ pé mo ti ṣẹ̀; Ìdí nìyí, tí ó fi jẹ́ pé èmi ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́ wá pàdé rẹ lónìí, ninu gbogbo ìdílé Josẹfu.”

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:14-26