Samuẹli Keji 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan lọ sọ fún Joabu pé, ọba ń sọkún, ó sì ń ṣọ̀fọ̀ Absalomu.

Samuẹli Keji 19

Samuẹli Keji 19:1-9