Samuẹli Keji 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun náà tàn káàkiri gbogbo agbègbè; àwọn tí wọ́n sì sọnù sinu igbó pọ̀ ju àwọn tí wọ́n fi idà pa lójú ogun lọ.

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:7-11