Samuẹli Keji 18:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ṣọ́ tún ní, “Ẹni tí ó ṣáájú tí mo rí yìí jọ Ahimaasi.”Ọba dáhùn pé, “Eniyan dáradára ni, ìròyìn ayọ̀ ni ó sì ń mú bọ̀.”

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:22-33