Samuẹli Keji 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pe ọba nísàlẹ̀, ó sì sọ fún un, ọba bá dáhùn pé, “Bí ó bá jẹ́ òun nìkan ni, ìròyìn ayọ̀ ni ó ń mú bọ̀.” Ẹni tí ń sáré bọ̀ náà túbọ̀ ń súnmọ́ tòsí.

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:21-33