Samuẹli Keji 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu bá sọ fún ọ̀kan ninu àwọn ará Kuṣi pé, “Lọ sọ ohun tí o rí fún ọba.” Ará Kuṣi náà bá tẹríba fún Joabu, ó sì sáré lọ.

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:15-26