Samuẹli Keji 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí mo bá ṣe àìgbọràn sí òfin ọba, tí mo sì pa Absalomu, ó pẹ́ ni, ó yá ni, ọba yóo gbọ́, bí ọba bá sì gbọ́, ìwọ gan-an kò ní gbà mí sílẹ̀.”

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:6-22