Samuẹli Keji 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi kó gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó pín wọn ní ọgọọgọrun-un (100) ati ẹgbẹẹgbẹrun (1,000), ó fi balogun kọ̀ọ̀kan ṣe olórí ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan.

Samuẹli Keji 18

Samuẹli Keji 18:1-11