Samuẹli Keji 17:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó ibùsùn lọ́wọ́ wá fún wọn, ati àwo, ìkòkò ati ọkà baali, ọkà tí wọ́n ti lọ̀, ati èyí tí wọ́n ti yan, erèé ati ẹ̀fọ́;

Samuẹli Keji 17

Samuẹli Keji 17:26-29