Samuẹli Keji 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Aya ọkunrin náà fi nǹkan dé e lórí, ó sì da ọkà bàbà lé e kí ẹnikẹ́ni má baà fura sí i.

Samuẹli Keji 17

Samuẹli Keji 17:10-26