Samuẹli Keji 17:12 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo kọlu Dafidi níbikíbi tí a bá ti bá a, a óo bò wọ́n bí ìgbà tí ìrì bá sẹ̀ sórí ilẹ̀; ẹnikẹ́ni kò sì ní yè ninu òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀.

Samuẹli Keji 17

Samuẹli Keji 17:11-19