Samuẹli Keji 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń sọ òkúta lu Dafidi ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn eniyan ńláńlá ati ọpọlọpọ eniyan mìíràn wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji Dafidi ọba.

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:1-7