Samuẹli Keji 16:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá pàgọ́ kan fún Absalomu, lórí òrùlé ààfin, ó wọlé lọ bá àwọn obinrin baba rẹ̀ lójú gbogbo àwọn eniyan, ó sì bá wọn lòpọ̀.

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:13-23