Samuẹli Keji 16:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Absalomu kọjú sí Ahitofeli, ó sì bi í pé, “Nígbà tí a ti dé Jerusalẹmu báyìí, kí ni ìmọ̀ràn rẹ?”

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:15-23