Samuẹli Keji 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo fi wà ní Geṣuri, ní ilẹ̀ Siria, mo jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA, pé bí ó bá mú mi pada sí Jerusalẹmu, n óo lọ sìn ín ní Heburoni.”

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:1-18