Samuẹli Keji 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá súnmọ́ Absalomu láti wólẹ̀, kí ó sì kí i tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀, Absalomu á tètè na ọwọ́ sí i, á gbá a mú, a sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:3-15