Samuẹli Keji 15:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ wọn mejeeji, Ahimaasi ati Jonatani wà lọ́dọ̀ wọn. Gbogbo ohun tí ẹ bá gbọ́, kí ẹ máa rán wọn sí mi.”

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:29-37