Samuẹli Keji 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Sadoku ati Abiatari bá gbé àpótí ẹ̀rí pada sí Jerusalẹmu, wọ́n sì wà níbẹ̀.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:20-30