Samuẹli Keji 15:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún fi kún un fún Sadoku pé, “Wò ó! Ìwọ ati Abiatari, ẹ pada sí ìlú ní alaafia, mú Ahimaasi, ọmọ rẹ, ati Jonatani ọmọ Abiatari lọ́wọ́.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:22-36