Samuẹli Keji 15:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi dáhùn, ó ní, “Kò burú.” Itai ati àwọn eniyan rẹ̀, ati àwọn ọmọ kéékèèké, tò kọjá níwájú ọba.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:13-27