Samuẹli Keji 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ sì ń tò kọjá níwájú rẹ̀; àwọn ẹgbẹta (600) ọmọ ogun tí wọ́n tẹ̀lé e láti Gati náà tò kọjá níwájú rẹ̀.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:10-27