Samuẹli Keji 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn èyí, Absalomu wá kẹ̀kẹ́ ogun kan, ati àwọn ẹṣin, ati aadọta ọkunrin tí wọn yóo máa sáré níwájú rẹ̀.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:1-8