Samuẹli Keji 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọkunrin meji ni mo bí. Ní ọjọ́ kan, àwọn mejeeji ń bá ara wọn jà ninu pápá, kò sì sí ẹnikẹ́ni nítòsí láti là wọ́n, ni ọ̀kan ninu wọn bá lu ekeji rẹ̀ pa.

Samuẹli Keji 14

Samuẹli Keji 14:1-14